JetBits |
! You are not logged in to JetBits. Please register or login.
* Itumoala > Forum
ainaoluwafemi
(1)TIO ba lala ripe oun ka mango... Itumo..wari ibunkun ati anu... (2)Tio ba lala ri ara re ninu odo tio si la odo naaja...itumo, wari ogun sugbon wa laaja. (3)TIO ba lala ri ara re ni ihoho...itumo, asiri ikoko re yio tu loju araye... (4)TIO ba lala ri ara ni iboji oku pelu awon oku...itumo, asiri kan nbe tia fefi han omo enia ... **So ala tire naa kio si gba itumo lati mo ona abayo si oro aye re
8 Replies 43 Views 0 Bookmarks
topics posts

* Itumoala Forum
fav Bookmarks

* Itumoala