
![]() |
@ainaoluwafemi | |
Good morning everyone..... Awon akanda eyan tio wa ninu aye... Tia ban soro nipa akanda..akanda je eniyan tabi alujonu abara meji tio ni agbara ati ase lati dari awon nkan miron ninu aye.... Opolopo eyan ama sowipe iro nla ni..kosi alujonu.. Hmmm arakunrin ati arabinrin.. Nje o mo wipe inu aye tia wayi..awa eniyan nikan ko lan gbenure.. Awon kan ngbe inu omi. Awon kan ngbe inu afefe pelu orisirisi ara bi olorun se dawa.... Gege bia timo wipe aye tin lo si opin... Tio mu opolopo omo eniyan tio ni iberu olorun mo..... Awon alujonu ati eda miron ni iberu olorun ju awa eniyan lo.. Pelu bi won se lagbara to.,....... salaye ala re kio si gba itumo kio le mo igbese tuntun ninu aye re.. |
||
0
Replies
9
Views
1 Bookmarks
|


